Johanu Kinni 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ni òpùrọ́ bí ẹni tí ó bá kọ̀ láti gbà pé Jesu ni Mesaya? Olúwarẹ̀ ni Alátakò Kristi, tí ó kọ Baba ati Ọmọ.

Johanu Kinni 2

Johanu Kinni 2:19-23