Johanu Kinni 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí gbogbo nǹkan tí ó wà ninu ayé: ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara, ìwòkúwò ojú ati afẹfẹyẹ̀yẹ̀ ayé kò wá láti ọ̀dọ̀ Baba bíkòṣe láti inú ayé.

Johanu Kinni 2

Johanu Kinni 2:8-17