Johanu Kinni 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ tí ó fi rán wa, tí à ń jẹ́ fun yín nìyí: pé ìmọ́lẹ̀ ni Ọlọrun, kò sí òkùnkùn ninu rẹ̀ rárá.

Johanu Kinni 1

Johanu Kinni 1:1-6