Johanu Kinni 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyè yìí farahàn, a ti rí i, a sì ń jẹ́rìí rẹ̀. Ìyè ainipẹkun yìí tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Baba, tí ó ti farahàn fún wa, ni a wá ń kéde fun yín.

Johanu Kinni 1

Johanu Kinni 1:1-6