Joẹli 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń gun odi ìlú,wọ́n ń sáré lórí odi.Wọ́n ń gun orí ilé wọlé,wọ́n gba ojú fèrèsé bẹ́ sinu ọ̀dẹ̀dẹ̀ bí olè.

Joẹli 2

Joẹli 2:1-17