Joẹli 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń sáré bí akọni,wọ́n ń fo ògiri bí ọmọ ogun.Wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́,ẹnikẹ́ni kò sì yà kúrò ní ọ̀nà tirẹ̀.

Joẹli 2

Joẹli 2:1-10