Joẹli 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìró wọn dàbí ìró kẹ̀kẹ́ ogun,wọ́n ń bẹ́ lórí àwọn òkè ńlá.Ìró wọn dàbí ìró iná tí ń jó pápá,bí ìgbà tí àwọn alágbára ọmọ ogun múra fún ogun.

Joẹli 2

Joẹli 2:1-8