Joẹli 2:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn gbogbo àwọn tí wọ́n bá ké pe orúkọ OLUWA ni a óo gbàlà.Àwọn kan yóo sá àsálà ní òkè Sioni,ní Jerusalẹmu, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ,àwọn tí OLUWA pè yóo sì wà lára àwọn tí wọn yóo sá àsálà.

Joẹli 2

Joẹli 2:29-32