Joẹli 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má bẹ̀rù, ẹ̀yin ẹranko inú igbó,nítorí ewéko gbogbo ni ó tutù,igi gbogbo ti so èso,igi ọ̀pọ̀tọ́ ati ọgbà àjàrà sì ti so jìnwìnnì.

Joẹli 2

Joẹli 2:20-24