Joẹli 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ̀rọ̀ níwájú àwọn ọmọ ogun rẹ̀,nítorí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ pọ̀ lọpọlọpọ,alágbára ni ẹni tí ń mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ.Ọjọ́ ńlá ati ọjọ́ ẹ̀rù ni ọjọ́ OLUWA!Ta ló lè faradà á?

Joẹli 2

Joẹli 2:2-15