Joẹli 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́, ẹ̀yin àgbà,ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ yìí!Ǹjẹ́ irú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti ṣẹlẹ̀ rí ní àkókò yín,tabi ní àkókò àwọn baba yín?

Joẹli 1

Joẹli 1:1-6