Joẹli 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹran ọ̀sìn ń kérora,àwọn agbo mààlúù dààmú,nítorí pé kò sí pápá oko fún wọn;àwọn agbo aguntan pàápàá dààmú.

Joẹli 1

Joẹli 1:9-20