Jobu 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó ṣí àwọn òkè nídìí, ninu ibinu rẹ̀;tí wọn kò sì mọ ẹni tí ó bì wọ́n ṣubú.

Jobu 9

Jobu 9:1-11