Jobu 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo wí pé,‘Ibùsùn mi yóo tù mí lára,ìjókòó mi yóo sì mú kí ara tù mí ninu ìráhùn mi’.

Jobu 7

Jobu 7:6-19