Jobu 7:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Ìgbésí ayé eniyan le koko,ọjọ́ ayé rẹ̀ sì dàbí ti alágbàṣe.

2. Ó dàbí ẹrú tí ń wá ìbòòji kiriati bí alágbàṣe tí ń dúró de owó iṣẹ́ rẹ̀.

3. Òfo ni ọ̀rọ̀ mi látoṣù-dóṣù,ìbànújẹ́ ní sì ń dé bá mi láti ọjọ́ dé ọjọ́

Jobu 7