Jobu 7:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Ìgbésí ayé eniyan le koko,ọjọ́ ayé rẹ̀ sì dàbí ti alágbàṣe.

2. Ó dàbí ẹrú tí ń wá ìbòòji kiriati bí alágbàṣe tí ń dúró de owó iṣẹ́ rẹ̀.

Jobu 7