Jobu 5:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Pe ẹnìkan nisinsinyii;ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni dá ọ lóhùn?Ẹni mímọ́ wo ni o lè tọ̀ lọ?

2. Dájúdájú ibinu a máa pa òmùgọ̀,owú jíjẹ a sì máa pa aláìmọ̀kan.

Jobu 5