Jobu 42:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Elifasi ará Temani, Bilidadi ará Ṣuha, ati Sofari ará Naama lọ ṣe ohun tí OLUWA sọ fún wọn, OLUWA sì gbọ́ adura Jobu.

Jobu 42

Jobu 42:1-17