Jobu 42:1-3 BIBELI MIMỌ (BM) Jobu bá dá OLUWA lóhùn ó ní: “Mo mọ̀ pé o lè ṣe ohun gbogbo,kò sì sí ohun tí ó lè da ìpinnu rẹ rú.