Jobu 39:6-8 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Mo fi inú pápá ṣe ilé rẹ̀,ilẹ̀ oníyọ̀ sì di ibùgbé rẹ̀.

7. Ó ń pẹ̀gàn ìdàrúdàpọ̀ inú ìlú ńlá,kò gbọ́ ariwo àwọn tí wọn ń fi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ṣiṣẹ́.

8. Ó ń rìn káàkiri àwọn òkè bí ibùjẹ rẹ̀,ó sì ń wá ewéko tútù kiri.

Jobu 39