Jobu 38:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Ta ló ṣe ìdíwọ̀n rẹ̀–ṣebí o mọ̀ ọ́n, dá mi lóhùn!Àbí ta ló ta okùn ìwọ̀n sórí rẹ̀?

6. Orí kí ni a gbé ìpìlẹ̀ rẹ̀ lé,àbí ta ló fi òkúta igun rẹ̀ sọlẹ̀;

7. tí àwọn ìràwọ̀ òwúrọ̀ ń jùmọ̀ kọrin,tí gbogbo àwọn ọmọ Ọlọrun sì búsáyọ̀?

Jobu 38