Jobu 38:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé o lè darí àkójọpọ̀ àwọn ìràwọ̀, ní àkókò wọn,tabi kí o ṣe atọ́nà ìràwọ̀ Beari ati àwọn ọmọ rẹ̀?

Jobu 38

Jobu 38:27-37