Jobu 38:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà náà ni OLUWA dá Jobu lóhùn láti inú ìjì líle.

2. Ó bi í pé,“Ta ni ẹni tí ń bu ẹnu àtẹ́ lu ìmọ̀ràn,tí ń sọ̀rọ̀ tí kò ní ìmọ̀?

Jobu 38