Jobu 37:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Nígbà tí mo gbọ́, ọkàn mi wárìrì,ó sì fò sókè ní ipò rẹ̀.

2. Gbọ́ ohùn rẹ̀ tí ń dún bí ààrá,ati ariwo tí ń ti ẹnu rẹ̀ jáde.

3. Ó rán mànàmáná rẹ̀ sí wọn jákèjádò ojú ọ̀run,títí dé òpin ilẹ̀ ayé.

Jobu 37