Jobu 36:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kìí mú ojú kúrò lára àwọn olódodo,ṣugbọn a máa gbé wọn sórí ìtẹ́ pẹlu àwọn ọba,á gbé wọn ga,á sì fi ìdí wọn múlẹ̀ títí lae.

Jobu 36

Jobu 36:4-17