Jobu 36:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá gbọ́ràn, tí wọ́n sì sìn ín,wọn yóo lo ọjọ́ ayé wọn pẹlu ìdẹ̀rùn,wọn yóo ṣe ọ̀pọ̀ ọdún ninu ìgbádùn.

Jobu 36

Jobu 36:5-21