Jobu 36:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Elihu tún tẹ̀síwájú ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní,

2. “Ní sùúrù fún mi díẹ̀, n óo ṣe àlàyé fún ọ,nítorí mo ní ohun kan tí mo fẹ́ gbẹnusọ fún Ọlọrun.

3. N óo gba ìmọ̀ mi láti ọ̀nà jíjìn,n óo sì fi júbà Ẹlẹ́dàá mi, tí ó ní ìmọ̀ òdodo.

Jobu 36