Jobu 35:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn eniyan ń kígbe nítorí ọpọlọpọ ìnira,wọ́n ń bẹ̀bẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́,nítorí àwọn alágbára ń tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀.

Jobu 35

Jobu 35:5-10