Jobu 32:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní,“Àgbàlagbà ni yín, ọmọde sì ni mí,nítorí náà ni ojú fi ń tì mí,tí ẹ̀rù sì ń bà mí láti sọ èrò ọkàn mi.

Jobu 32

Jobu 32:1-8