Jobu 31:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọkàn mi bá fà sí obinrin olobinrin,tabi kí n máa pẹ́ kọ̀rọ̀ lẹ́nu ọ̀nà aládùúgbò mi;

Jobu 31

Jobu 31:2-10