Jobu 30:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Àwọ̀ ara mi di dúdú, ó ń bó,egungun mi gbóná fún ooru.

31. Ọ̀fọ̀ dípò orin ayọ̀ fún mi,ẹkún sì dípò ohùn fèrè.

Jobu 30