Jobu 30:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí mo ti sọkún nítorí àwọn tí wọ́n wà ninu ìṣòro rí,tí mo sì káàánú àwọn aláìní.

Jobu 30

Jobu 30:21-27