Jobu 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ìràwọ̀ òwúrọ̀ rẹ̀ ṣókùnkùn,kí ìrètí rẹ̀ fún ìmọ́lẹ̀ àfẹ̀mọ́júmọ́ já sí òfo,kí ó má rí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ mọ́;

Jobu 3

Jobu 3:3-15