Jobu 27:1-3 BIBELI MIMỌ (BM) Jobu tún dáhùn pé, “Mo fi Ọlọrun tí ó gba ẹ̀tọ́ mi búra,mo fi Olodumare tí ó mú kí ọkàn mi bàjẹ́