Jobu 24:24-25 BIBELI MIMỌ (BM)

24. A gbé wọn ga fún ìgbà díẹ̀,lẹ́yìn náà, a rẹ̀ wọ́n sílẹ̀,wọn á rọ, wọn á sì rẹ̀ dànù bí ewé,a ké wọn kúrò bí orí ọkà bàbà.

25. Bí kò bá rí bẹ́ẹ̀, kí ẹnìkan já mi nírọ́,kí ó sì fi hàn pé ìsọkúsọ ni mò ń sọ.”

Jobu 24