Jobu 22:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Ṣé nítorí pé o bẹ̀rù rẹ̀ ni ó ṣe bá ọ wí,tí ó sì ń dá ọ lẹ́jọ́?

5. Ṣebí ìwà ibi rẹ ló pọ̀;tí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kò sì lópin?

6. O gba nǹkan ìdógò lọ́wọ́ àwọn arakunrin rẹ láìnídìí,O bọ́ wọn sí ìhòòhò goloto.

Jobu 22