Jobu 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ǹjẹ́ eniyan lè wúlò fún Ọlọrun?Nítòótọ́, bí eniyan tilẹ̀ jẹ́ ọlọ́gbọ́n, ara rẹ̀ ni ó wúlò fún.

Jobu 22

Jobu 22:1-10