Jobu 21:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ẹnìkan lè kọ́ Ọlọrun ní ìmọ̀,nígbà tí ó jẹ́ pé òun ni onídàájọ́ àwọn tí wọ́n wà ní ibi gíga?

Jobu 21

Jobu 21:16-29