Jobu 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

pé bí inú eniyan burúkú bá ń dùn,tí ẹni tí kò mọ Ọlọrun bá ń yọ̀, fún ìgbà díẹ̀ ni.

Jobu 20

Jobu 20:1-13