Jobu 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tún yá tí àwọn ọmọ Ọlọrun wá farahàn níwájú OLUWA, Satani náà wà láàrin wọn.

Jobu 2

Jobu 2:1-11