Jobu 19:11-13 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Ibinu rẹ̀ ń jó mi bí iná,ó kà mí kún ọ̀tá rẹ̀.

12. Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ kó ara wọn jọ,wọ́n dó tì mí,wọ́n sì pa àgọ́ tiwọn yí àgọ́ mi ká.

13. “Ó mú kí àwọn arakunrin mi jìnnà sí mi,àwọn ojúlùmọ̀ mi sì di àjèjì sí mi.

Jobu 19