Jobu 18:7-11 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Agbára rẹ̀ ti dín kù,ète rẹ̀ sì gbé e ṣubú.

8. Ó ti ẹsẹ̀ ara rẹ̀ bọ àwọ̀n,ó ń rìn lórí ọ̀fìn.

9. Tàkúté ti mú un ní gìgísẹ̀,ó ti kó sinu pańpẹ́.

10. A dẹ okùn sílẹ̀ fún un,a sì dẹ pańpẹ́ sí ojú ọ̀nà rẹ̀.

11. “Ìbẹ̀rù yí i ká,wọ́n ń lé e kiri.

Jobu 18