Jobu 18:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Ìwọ tí o faraya nítorí inú ń bí ọ,ṣé kí á sá kúrò láyé nítorí rẹ ni,tabi kí á ṣí àwọn àpáta nípò pada?

5. “Nítòótọ́, a ti pa fìtílà ẹni ibi,ahọ́n iná rẹ̀ kò sì mọ́lẹ̀ mọ́.

6. Inú àgọ́ rẹ̀ ṣókùnkùn,a sì ti pa àtùpà ìgbèrí rẹ̀.

Jobu 18