Jobu 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu yóo ya àwọn ará ìwọ̀ oòrùn,ìwárìrì yóo sì mú àwọn ará ìlà oòrùn,nítorí ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí i.

Jobu 18

Jobu 18:13-21