Jobu 18:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìgbàwo ni o óo sinmi ẹjọ́ tí ò ń tò yìí?Ohun tí a tí ń bá ọ sọ ni kí o gbé yẹ̀wò,kí á lè sọ èyí tí a tún fẹ́ sọ.

Jobu 18

Jobu 18:1-10