Jobu 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ ni ó ń fa irú ọ̀rọ̀ tí ń ti ẹnu rẹ jáde,ètè rẹ sì kún fún àrékérekè.

Jobu 15

Jobu 15:2-9