Jobu 15:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ni eniyan jẹ́, tí ó fi lè mọ́ níwájú Ọlọrun?Kí ni ẹnikẹ́ni tí obinrin bí já mọ́, tí ó fi lè jẹ́ olódodo?

Jobu 15

Jobu 15:10-20