Jobu 15:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n hu ewú lórí wà láàrin wa, ati àwọn àgbàlagbà,àwọn tí wọ́n dàgbà ju baba rẹ lọ.

Jobu 15

Jobu 15:2-11