Jobu 15:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Elifasi ará Temani bá dáhùn pé,

2. “Ṣé ọlọ́gbọ́n a máa fọ èsì tí kò mọ́gbọ́n lọ́wọ́?Kí ó dàbí àgbá òfìfo?

3. Kí ó máa jiyàn lórí ọ̀rọ̀ tí kò wúlò,tabi ọ̀rọ̀ tí kò níláárí?

Jobu 15