Jobu 15:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Elifasi ará Temani bá dáhùn pé,

2. “Ṣé ọlọ́gbọ́n a máa fọ èsì tí kò mọ́gbọ́n lọ́wọ́?Kí ó dàbí àgbá òfìfo?

Jobu 15